Àgbéyẹ̀wò Àṣà Ìbéyàwó ní Kákùmọ̀ Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òǹdó
Iṣẹ́ yìí ṣe àgbéyẹ̀ wò ìyàtọ̀ tó wà nínú àṣà ìgbéyàwó ní ìlú Kákùmọ̀ sí ti agbègbè ilẹ̀ Yorùbá mìíràn; a fi tíọ́ rì ìfojú-àṣà-ìbílẹ̀ -wò àti tíọ́ rì ìṣẹ̀ tọ́ fábo ṣe àtẹ̀ gùn. A lo ọgbọ́ n ìfọ̀ rọ̀ wánilẹ́ nuwò, a sì ka àkọsílẹ̀ ìtàn ìlú Kákùmọ̀ . Àbájáde ìwádìí fi hàn pé àgbékalẹ̀ ètò ìgbéyàwó ìlú...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130105 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|