Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n koju awon oluko ati akekoo ede Yoruba ni orile-ede naa, ki o too wa wo sakun ojo-ola eto eko naa nile Amerika. Lara awon aba ti apileko yii gbe kale ki ojo-olo ede Yoruba le dara sii ni: kiko iwe iko...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Akintunde Akinyemi
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130150
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!