Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè (linguistics) àti lítíréṣọ̀ ti wọnú ara wọn tí ó jẹ́ pé a fẹ́ rẹ̀ má le ya ọ̀ kan kúrò lára èkejì. Èròǹgbà iṣẹ́ yìí ni láti fi ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàárin ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti lítíréṣọ hán. Láti ṣe èyí a yan ìwé-ìtàn –àròsọ Àjà Ló Lẹrù tí Òkédìjí kọ láàyò, a sì fi ẹ̀ka -ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mọ...
Saved in:
| Main Authors: | , |
|---|---|
| Format: | Article |
| Language: | English |
| Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
| Series: | Yoruba Studies Review |
| Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130089 |
| Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
| _version_ | 1849337176438865920 |
|---|---|
| author | Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀ |
| author_facet | Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀ |
| author_sort | Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè |
| collection | DOAJ |
| description |
Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè (linguistics) àti lítíréṣọ̀ ti wọnú ara wọn tí ó jẹ́ pé a fẹ́ rẹ̀ má le ya ọ̀ kan kúrò lára èkejì. Èròǹgbà iṣẹ́ yìí ni láti fi ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàárin ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti lítíréṣọ hán. Láti ṣe èyí a yan ìwé-ìtàn –àròsọ Àjà Ló Lẹrù tí Òkédìjí kọ láàyò, a sì fi ẹ̀ka -ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mọfọ́lọ́jì tí í ṣe ẹ̀kọ́ ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ṣe àyẹ̀wò ìlò ọ̀rọ̀-orúkọ (OR) aṣẹ̀dá nínú ìwé ìtàn-àròsọ yìí. Lára ọgbọ́n ìwádìí tí a lò ni pé a ka ìwé ìtàn àròsọ Àjà Ló Lẹrù dáadáa, a sì ṣe àfàyọ àwọn OR aṣẹ̀dá jáde nínú rẹ̀. Lẹ́yìn èyí ni a ṣe àkójọpọ̀ àti ìtúpalẹ̀ àwọn OR aṣẹ̀dá wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìlànà ìṣẹ̀dá wọn nínú ẹ̀kọ́ mọfọ́lọ́jì. A ṣe àyẹ̀wò àwọn iṣẹ́ tí ó jẹ mọ́ mọfọ́lọ́jì àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìsọwọ́lò-èdè àti lítíréṣọ̀ (stylistics) láti mú kí iṣẹ́ yìí kún ojú òsùnwọ̀n. Ní ìparí iṣẹ́ yìí, a rí i pé ipa tí ìlò àwọn OR aṣẹ̀ dá nínú ìwé ìtàn-àrosọ yìí kó kò kéré rárá. Àwọn OR aṣẹ̀dá yìí jẹ́ èròjà tí ó mú èdè ìwé náà kún, kí ó ki tí ó sì fi àwòrán àwọn ẹ̀dá ìtàn rẹ̀ hàn. Bí kò bá sí àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ lítíréṣọ̀, ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ aṣẹ̀dá pàápàá OR nínu ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ni kò ní wúlò bí a ṣe rí i nínú iṣẹ́ àpilẹ̀ kọ yíí. Lítíréṣọ̀ tún wá di orísun àfikún àká ọ̀ rọ̀ nínú ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè.
|
| format | Article |
| id | doaj-art-1b93e45804464a20b75377ae2021aca0 |
| institution | Kabale University |
| issn | 2473-4713 2578-692X |
| language | English |
| publishDate | 2021-12-01 |
| publisher | LibraryPress@UF |
| record_format | Article |
| series | Yoruba Studies Review |
| spelling | doaj-art-1b93e45804464a20b75377ae2021aca02025-08-20T03:44:46ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló LẹrùFolúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè 0Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀ 1University of ÌlọrinUniversity of Ìlọrin Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè (linguistics) àti lítíréṣọ̀ ti wọnú ara wọn tí ó jẹ́ pé a fẹ́ rẹ̀ má le ya ọ̀ kan kúrò lára èkejì. Èròǹgbà iṣẹ́ yìí ni láti fi ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàárin ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti lítíréṣọ hán. Láti ṣe èyí a yan ìwé-ìtàn –àròsọ Àjà Ló Lẹrù tí Òkédìjí kọ láàyò, a sì fi ẹ̀ka -ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mọfọ́lọ́jì tí í ṣe ẹ̀kọ́ ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ṣe àyẹ̀wò ìlò ọ̀rọ̀-orúkọ (OR) aṣẹ̀dá nínú ìwé ìtàn-àròsọ yìí. Lára ọgbọ́n ìwádìí tí a lò ni pé a ka ìwé ìtàn àròsọ Àjà Ló Lẹrù dáadáa, a sì ṣe àfàyọ àwọn OR aṣẹ̀dá jáde nínú rẹ̀. Lẹ́yìn èyí ni a ṣe àkójọpọ̀ àti ìtúpalẹ̀ àwọn OR aṣẹ̀dá wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìlànà ìṣẹ̀dá wọn nínú ẹ̀kọ́ mọfọ́lọ́jì. A ṣe àyẹ̀wò àwọn iṣẹ́ tí ó jẹ mọ́ mọfọ́lọ́jì àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìsọwọ́lò-èdè àti lítíréṣọ̀ (stylistics) láti mú kí iṣẹ́ yìí kún ojú òsùnwọ̀n. Ní ìparí iṣẹ́ yìí, a rí i pé ipa tí ìlò àwọn OR aṣẹ̀ dá nínú ìwé ìtàn-àrosọ yìí kó kò kéré rárá. Àwọn OR aṣẹ̀dá yìí jẹ́ èròjà tí ó mú èdè ìwé náà kún, kí ó ki tí ó sì fi àwòrán àwọn ẹ̀dá ìtàn rẹ̀ hàn. Bí kò bá sí àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ lítíréṣọ̀, ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ aṣẹ̀dá pàápàá OR nínu ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ni kò ní wúlò bí a ṣe rí i nínú iṣẹ́ àpilẹ̀ kọ yíí. Lítíréṣọ̀ tún wá di orísun àfikún àká ọ̀ rọ̀ nínú ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130089 |
| spellingShingle | Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀ Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù Yoruba Studies Review |
| title | Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù |
| title_full | Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù |
| title_fullStr | Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù |
| title_full_unstemmed | Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù |
| title_short | Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù |
| title_sort | aye ̀wo ilo apola oruko aseda ninu iwe itanaroso aja lo leru |
| url | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130089 |
| work_keys_str_mv | AT folukebolanleadekeye ayewoiloapolaorukoasedaninuiweitanarosoajaloleru AT bolanleelizabetharokoyo ayewoiloapolaorukoasedaninuiweitanarosoajaloleru |