Suggested Topics within your search.
Suggested Topics within your search.
- History 21
- Management 20
- Politics and government 16
- Research 15
- Tourism 15
- Methodology 12
- Moral and ethical aspects 12
- Economic conditions 10
- Torts 10
- methods 10
- Economic development 9
- English language 9
- Information technology 9
- Economic policy 8
- Hospitality industry 8
- Law 8
- Social conditions 8
- Biochemistry 7
- English 7
- Mass media 7
- Philosophy 7
- Psychology 7
- Social aspects 7
- Women 7
- Constitutional law 6
- History and criticism 6
- Personnel management 6
- Sociology 6
- Business enterprises 5
- Economics 5
-
20701
Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì
Published 2021-12-01“…Èyí jẹ́ kí a ní òye pé, takọ-tabo ló ni ipa tí wọ́ n ń kó nínú ọdún àti bíbọ ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn, bẹ́ ẹ̀ ni a rí ihà tí obìnrin kọ sí ọkùnrin, ìhà tí ọkùnrin kọ sí obìnrin, àti ìhà tí àwọn obìnrin kọ sí ara wọn ní ojúbọ. Ohun gbogbo tí a tọ́ ka sí nípa ewì alohùn Aláwòrò-Ẹkùn àti ìlò ohun èlò pọ̀ mọ́ ewì alohùn wọ̀ nyí jẹ́ kí a lè sọ pé ipa pàtàkì ni àwọn ewì alohùn ń kó nínú bíbọ ìbọ àti ọdún láwùjọ Yorùbá, àti ní pàtàkì jùlọ nínú ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ̀ Èkó. …”
Get full text
Article -
20702
Wútùwútù Yáákí
Published 2021-12-01“…Méjì ̣ ni àwọn onímò -èdè Yorùbá tó ti yẹ ẹsẹ Ifá wò fínífíní pe ̣ ̀ lú ìjìnle ̣ ̀ ìmọ̀ òde òní ̣ nípa èdè tí a ń pè ní lìǹgúísítíkì. …”
Get full text
Article -
20703
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Published 2021-12-01“…Iṣẹ́ yìí ṣàfihàn pé iṣẹ́ ọpọlọ tó jinná ni orin kíkọ àti pé àwọn ọnà-èdè tó máa ń ṣodo sínú wọn lóríṣiríṣi ní iṣẹ́ tí kálukú wọn ń jẹ́ láti túdìí òkodoro nípa àṣà, ìṣe àti èdè àwùjọ tí onírúurú àwọn orin náà ti ń jáde …”
Get full text
Article -
20704
Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
Published 2021-12-01“…A ṣàwárí pé oríṣìí mẹ́ tà ọ̀ tọ̀ ọ̀ tọ̀ ni irú àwọn ọ̀ rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wà wọ àwọn ọ̀ rọ̀ náà lọ́ rùn. …”
Get full text
Article -
20705
Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
Published 2021-12-01“…Ìwádìí yìí fi àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú hàn gẹ́gẹ́ bí èyí tí àkóónú rẹ̀ kún fún onírúurú ìtàn nípa ètò-ìṣèlú ilẹ̀ Ìjẹ̀bú, ètò-ọrọ̀-ajé àti àṣà tí ó jẹ mọ́ ètò-ìbára-ẹni-gbépọ̀ àwùjọ Ìjẹ̀bú gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà kan tó ní ọlá láwùjọ Yorùbá. Gbogbo àwọn nǹkan tí ìwádìí yìí ṣe àfàyọ rẹ̀ nínú àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ilè Ìjè ̣ bú ni kò fi bẹ́ẹ̀ fara hàn nínú iṣẹ́ àwọn ̣ onímọ̀ ìṣáájú nípa oríkì ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. …”
Get full text
Article -
20706
Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
Published 2021-12-01“…Nínú ìfọr̀ọwánil ̀ ẹnuwò yìí, ́ Olóyè Òkédìjí mẹnuba ́ ọgbọn ìs ́ ọtàn w ̀ ọn, ìṣòro tó ń dojúkọ lítíréṣọ̀ Yorùbá, àtí ìpèníjà tó dé bá jíjẹ ò́ ǹkọwé alátinúdá ní àwùj ̀ ọ wa, àti ní orílẹ-èdè Nàíjíríà. …”
Get full text
Article -
20707
Ìtúpalẹ ̀ Àṣàyàn Oríkì Ẹranko
Published 2021-12-01“…A ṣe àkójọpò oríkì àwọn àṣàyàn ẹranko tí a gbà síle ̣ ̀ bí wo ̣ ́ n ṣe jẹ yọ nínú ̣ ìjálá àti ìrèmò jé tó je ̣ ̣ ́ lítíréṣò alohùn tí a mo ̣ ̀ mo ̣ ́ àwọn ọdẹ. …”
Get full text
Article -
20708
Àgbéyẹ̀wò Àṣà Ìbéyàwó ní Kákùmọ̀ Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òǹdó
Published 2021-12-01“… Iṣẹ́ yìí ṣe àgbéyẹ̀ wò ìyàtọ̀ tó wà nínú àṣà ìgbéyàwó ní ìlú Kákùmọ̀ sí ti agbègbè ilẹ̀ Yorùbá mìíràn; a fi tíọ́ rì ìfojú-àṣà-ìbílẹ̀ -wò àti tíọ́ rì ìṣẹ̀ tọ́ fábo ṣe àtẹ̀ gùn. …”
Get full text
Article -
20709
Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
Published 2021-12-01“…Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀ wò ìlò èébú nínú ìtàn-àròsọ Òkédìjí, ó sì lo ọgbọ́ n ìwádìí kíka àwọn ìwé náà ní àkàtúnkà láti ṣe àfàyọ àti àkójọpọ̀ gbogbo èébú tó súyọ kí a tó ṣe ìtúpalẹ̀ wọn. Tíọ́rì ọ̀nà ìṣafọ̀ tó jẹmọ́ èròǹgbà aṣafọ̀ àti ìmọ̀lára òsùnsùn-afọ̀ nípa afọ̀ la fi ṣe àlàyé wa. …”
Get full text
Article -
20710
̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
Published 2021-12-01“…Tíó̩ rì aje̩ mó̩ s̩ e-o̩ kàn tó dá lórí ìko̩ lura ninú o̩ po̩ lo̩ àti ìs̩ àkóso rè ̩ ni a lò, èyí tó s̩ àfihàn wíwá ìtumò̩ ìjìnlè ̩ sí ìhùwàsí ènìyàn. …”
Get full text
Article -
20711
Àkànlò-èdè Tuntun Nínú Àwọn Orin Ọ ̀ dọ ́ Ìwòyí
Published 2021-12-01“…Ọ̣ ̀pòḷọpo ̣ ̀ ̀ iṣe ̣ ̣ ́ ìwádìí ní ó ti wà lórí ìṣàmúlò àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin, fíìmù àgbéléwò, ìpolówó ọjà, ìròyìn, o ̣ ̀ nà ìbániso ̣ ̀ ro ̣ ̀ nínú eré boòlù àfẹse ̣ ̣ ̀ gbá láàrin àwọn èrò ìwòran ní gbàgede ìwòran àti ìgbòkègbodò ọko ̣ ̀ ṣùgbó n kò fi bee ̣ ̀ sí iṣé tí ó jinle ̣ ̣ ̀ lórí ìjẹyọ àkànlò èdè Yorùbá tuntun nínú orin tàka-súfèé òde òní èyí tó wo ̣ ́ po ̣ ̀ láàrin àwọn o ̣ ̀ do ̣ ́ . …”
Get full text
Article -
20712
Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
Published 2021-12-01“…Àwọn èèyàn tó màṣà tó mèdè, tó mẹni màṣà mèdè, Gbogbo wọn ń dárò ẹni ire tó lọ! …”
Get full text
Article -
20713
Ewì Gẹ́gẹ́ Bí Ètè Ogun Jíjà Láwùjọ
Published 2021-12-01“…Nítorí náà, ewì tí í ṣe ogún ìbí Yorùbá ni a le ṣàmúlò láti dènà tàbí pẹ̀tù sí aáwọ̀ kí ó tó di ogun lọ́ nà àti mú àlàáfíà àti ìdàgbàsókè bá àwùjọ. …”
Get full text
Article -
20714
Adébáyọ̀ Fálétí Dará Ilẹ
Published 2021-12-01“… Àkàndé ìjí, Ọlọyẹ́ moyin òòò ́ Ojú kan ní í bíni Igba ní í woni dàgbà Ìwọ nìkàn, Elétùú, Ọdẹ orófó Mọlọyẹ́ moyin, Ọdẹ àdàbà ́ O jọgọrùn-ún baba fúnrúu wa ́ Ìwọ òjìnmí onímọ̀ àṣà àtèdè Ọ̀kàn ni mí lára òròmọdìẹ Tó ó kọ́ ní Fáfitì ẹlẹrankoòlúùbàdàn ́ Ọ̀kàn ni mi lára ọ̀jẹ̀ wẹwẹ ́ ́ olùwadìí Tó o bùn nímọ̀ mu Láti inú òdù àmù ikùn Baba onínúure, tó jàpapọ̀ baba ẹlòmíìn Baba mi, Pa-nílé-o-tó-roko Kò sí ká lọ ká bọ̀ lọrọ́ ̀ tirẹ Ìwọ lo pa, pa, pa Tó o pèyí tí í pa baálé rẹ ládìẹ jẹ o tó roko Kánmọ-ń-kíá lò ó dáni lóhùn ́ Ní gbogbo ọjọ́ tá a báwadìí wọ́dọ̀ rẹ Àkàndé, aráàjíléje …”
Get full text
Article -
20715
Àgbéyẹ̀wò Ipa àti Ipò Àwọn Ọmọdé Nínú Ìpohùn Òrìṣà Ẹgbẹ́ Ọ̀gbà ní Agbègbè Yewa-Awórì, Ẹ̀gbá, àti Ìjẹ̀bú
Published 2021-12-01“…A tún ṣe àyẹ̀wò ìwé àpilẹ̀kọ, jọ́nà àti ẹ̀rọ-ayélujára lórí oríṣìí àwọn iṣẹ́ ìwádìí tó jẹ mọ́ lítíréṣọ̀ alohùn àwọn ọmọdé. Àwọn Ìpohùn tí a gbà jọ ní oko ìwádìí ni a ṣe ìtúpalẹ̀ wọn ní ìbámu pẹ̀lú àfojúsùn àwọn agbátẹrù ìfojú-ìmọ̀-ìbára-ẹni-gbépọ̀-wo-ìlò-àmì ti Amber àti Haque (2004). …”
Get full text
Article -
20716
-
20717
Ìṣọwọ́lò Ète Ìfèdèyàwòrán Nínú Ìpolówó Ọjà Lórí Rédíò
Published 2021-12-01“…Nítorí náà, a gba àwọn apolówó ọjà níyànjú láti máa ṣe àmúlò èdè tó ṣàfihàn ète ìfèdèyàwòrán. …”
Get full text
Article