Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun...
Saved in:
| Main Author: | |
|---|---|
| Format: | Article |
| Language: | English |
| Published: |
LibraryPress@UF
2023-05-01
|
| Series: | Yoruba Studies Review |
| Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097 |
| Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Be the first to leave a comment!