Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun...
Saved in:
| Main Author: | |
|---|---|
| Format: | Article |
| Language: | English |
| Published: |
LibraryPress@UF
2023-05-01
|
| Series: | Yoruba Studies Review |
| Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097 |
| Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
| _version_ | 1849237390718140416 |
|---|---|
| author | ‘Gbenga Adeoba |
| author_facet | ‘Gbenga Adeoba |
| author_sort | ‘Gbenga Adeoba |
| collection | DOAJ |
| description |
Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí gẹ́ gẹ́ bíi iṣẹ́ ọnà tí ó wúlò fún ìṣèwádìí iṣẹ́ ìtàn Nollywood ní ọ̀ nà tí ó yàtò. Ní oríṣiríṣi ọ̀ nà, iṣẹ́ yìí ń lo àwọn ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí láti ṣe àgbékalè ìtàn àwọn ohun ìkéde tí ó ṣe àmúlò àwọn nǹkan tí ó jé tiwantiwa. Ní ìtají sí bí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí ti ṣe ń di àwátì, iṣẹ́ yìí ń ṣe àmúlò àwọn ìtẹ̀ síwájú tí ó pemọ́ ìmọ̀ ẹ̀ rọ láti wo àwọn ọ̀ nà míràn tí a lè gbà se iṣẹ́ ìwádìí ìtàn tàbí se àgbéyèwò àṣà àti ìṣe ní ilè Africa. Nípasẹ̀ àmúlò ohun àgbéjáde ayélujára, Digital Nollywood ní èrò láti di iṣẹ́ ìwádìí dígítà tí ó ń ṣe ìdásí àti ìtẹ́ pẹpẹ ìwé àlẹ̀ móde àwọn fíìmù Nollywood nípasẹ̀ àgbàjọ àwọn ìwé wọ̀ nyí ní orí pẹpẹ Omeka.
|
| format | Article |
| id | doaj-art-e50ac2613f084b66804416456f1bfe2e |
| institution | Kabale University |
| issn | 2473-4713 2578-692X |
| language | English |
| publishDate | 2023-05-01 |
| publisher | LibraryPress@UF |
| record_format | Article |
| series | Yoruba Studies Review |
| spelling | doaj-art-e50ac2613f084b66804416456f1bfe2e2025-08-20T04:02:00ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2023-05-0181 Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìg씑Gbenga Adeoba0Washington University in St. Louis Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí gẹ́ gẹ́ bíi iṣẹ́ ọnà tí ó wúlò fún ìṣèwádìí iṣẹ́ ìtàn Nollywood ní ọ̀ nà tí ó yàtò. Ní oríṣiríṣi ọ̀ nà, iṣẹ́ yìí ń lo àwọn ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí láti ṣe àgbékalè ìtàn àwọn ohun ìkéde tí ó ṣe àmúlò àwọn nǹkan tí ó jé tiwantiwa. Ní ìtají sí bí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí ti ṣe ń di àwátì, iṣẹ́ yìí ń ṣe àmúlò àwọn ìtẹ̀ síwájú tí ó pemọ́ ìmọ̀ ẹ̀ rọ láti wo àwọn ọ̀ nà míràn tí a lè gbà se iṣẹ́ ìwádìí ìtàn tàbí se àgbéyèwò àṣà àti ìṣe ní ilè Africa. Nípasẹ̀ àmúlò ohun àgbéjáde ayélujára, Digital Nollywood ní èrò láti di iṣẹ́ ìwádìí dígítà tí ó ń ṣe ìdásí àti ìtẹ́ pẹpẹ ìwé àlẹ̀ móde àwọn fíìmù Nollywood nípasẹ̀ àgbàjọ àwọn ìwé wọ̀ nyí ní orí pẹpẹ Omeka. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097 |
| spellingShingle | ‘Gbenga Adeoba Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì” Yoruba Studies Review |
| title | Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì” |
| title_full | Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì” |
| title_fullStr | Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì” |
| title_full_unstemmed | Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì” |
| title_short | Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì” |
| title_sort | agbeyewo digital nollywood o ro lati enu awon agba osere ati ogbontarigi |
| url | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097 |
| work_keys_str_mv | AT gbengaadeoba agbeyewodigitalnollywoodorolatienuawonagbaosereatiogbontarigi |