Oríṣiríṣi àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ ní Kíláàsì Yorùbá fún Àjòjì àti oríṣi àwọn ọ̀nà Ìkédè wọn
Ijapa bo, o ni ohun ti eniyan ba moo se, bi idan nii ri. Amo sa, ki i le se ohunkohun lo dabi idan, igbaradi ati ipalemo to ye se pataki pupo. Ninu apileko yii, a o soro nipa okan pataki ninu awom eroja ti o se koko fun kiko ajoji ni ede ati asa Yoruba ni akoyege. Eroja yi ni ise ti oluko kookan gb...
Saved in:
Main Author: | Akinloye Ojo |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130141 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Similar Items
-
Àìgbọ́ àti àìlèsọ èdè Yorùbá àti àbáyọ fún àwọn ọmọ Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
by: Fehintola Mosadomi
Published: (2021-12-01) -
Àjùmọ̀ṣe àti Ìgbélárugẹ Èdè Yorùbá fún Ìkọ́ni ní oríṣiríṣi ẹ̀kọ́
by: Taiwo Olunlade
Published: (2021-12-01) -
Àgbéyẹ̀wò Ipa àti Ipò Àwọn Ọmọdé Nínú Ìpohùn Òrìṣà Ẹgbẹ́ Ọ̀gbà ní Agbègbè Yewa-Awórì, Ẹ̀gbá, àti Ìjẹ̀bú
by: Sauban Alade Isola
Published: (2021-12-01) -
Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
by: ‘Gbenga Adeoba
Published: (2023-05-01) -
Èdè Yorùbá, ọ̀rọ̀ àyálò, àti ọ̀rọ̀ àdàpọ̀ àti akẹ́kọ̀ọ́ kíkọ́ ní ìlú Amẹ́ríkà
by: Victor Temitope Alabi
Published: (2021-12-01)