Adébáyọ̀ Fálétí Dará Ilẹ

Àkàndé ìjí, Ọlọyẹ́ moyin òòò ́ Ojú kan ní í bíni Igba ní í woni dàgbà Ìwọ nìkàn, Elétùú, Ọdẹ orófó Mọlọyẹ́ moyin, Ọdẹ àdàbà ́ O jọgọrùn-ún baba fúnrúu wa ́ Ìwọ òjìnmí onímọ̀ àṣà àtèdè Ọ̀kàn ni mí lára òròmọdìẹ Tó ó kọ́ ní Fáfitì ẹlẹrankoòlúùbàdàn ́ Ọ̀kàn ni mi lára ọ̀jẹ̀ wẹwẹ ́ ́ olùwadìí Tó o bùn...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Adedotun Ogundeji (Àtàrí Àjààkú)
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130005
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
Description
Summary:Àkàndé ìjí, Ọlọyẹ́ moyin òòò ́ Ojú kan ní í bíni Igba ní í woni dàgbà Ìwọ nìkàn, Elétùú, Ọdẹ orófó Mọlọyẹ́ moyin, Ọdẹ àdàbà ́ O jọgọrùn-ún baba fúnrúu wa ́ Ìwọ òjìnmí onímọ̀ àṣà àtèdè Ọ̀kàn ni mí lára òròmọdìẹ Tó ó kọ́ ní Fáfitì ẹlẹrankoòlúùbàdàn ́ Ọ̀kàn ni mi lára ọ̀jẹ̀ wẹwẹ ́ ́ olùwadìí Tó o bùn nímọ̀ mu Láti inú òdù àmù ikùn Baba onínúure, tó jàpapọ̀ baba ẹlòmíìn Baba mi, Pa-nílé-o-tó-roko Kò sí ká lọ ká bọ̀ lọrọ́ ̀ tirẹ Ìwọ lo pa, pa, pa Tó o pèyí tí í pa baálé rẹ ládìẹ jẹ o tó roko Kánmọ-ń-kíá lò ó dáni lóhùn ́ Ní gbogbo ọjọ́ tá a báwadìí wọ́dọ̀ rẹ Àkàndé, aráàjíléje
ISSN:2473-4713
2578-692X