Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
Àrokò jẹ́ ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ nípa ṣíṣàmúlò àmì tàbí èdè awo. Ìran Yorùbá ò fẹ́ ràn láti máa fi gbogbo ẹnu sọ̀ rọ̀ , nítorí náà wọ́ n nífẹ̀ ẹ́ sí lílo èdè ìjìnlẹ̀ tàbí ohun tí ó ní ìtumọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú àṣà wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ . Ọ̀pọ̀ lọpọ̀ onímọ̀ tí ṣiṣẹ́ lórí pàtàkì àrokò láàárín àwọn Yorùbá àmọ́ ọ...
Saved in:
Main Author: | Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́ |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130094 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Similar Items
-
Ewì Gẹ́gẹ́ Bí Ètè Ogun Jíjà Láwùjọ
by: Luqman Abísọ́lá Kíaríbẹ̀ẹ́
Published: (2021-12-01) -
Kíkọ́ èdè Yorùbá Gẹ́gẹ́ bí Èdè Abínibí: Àkóónú àti ọgbọ́n Ìkọ́ni
by: Solomon Olanrewaju Makinde
Published: (2021-12-01) -
Àkànlò-èdè Tuntun Nínú Àwọn Orin Ọ ̀ dọ ́ Ìwòyí
by: Dayo Akanmu
Published: (2021-12-01) -
Oríṣiríṣi àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ ní Kíláàsì Yorùbá fún Àjòjì àti oríṣi àwọn ọ̀nà Ìkédè wọn
by: Akinloye Ojo
Published: (2021-12-01) -
Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
by: ‘Gbenga Adeoba
Published: (2023-05-01)