Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo

Àrokò jẹ́ ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ nípa ṣíṣàmúlò àmì tàbí èdè awo. Ìran Yorùbá ò fẹ́ ràn láti máa fi gbogbo ẹnu sọ̀ rọ̀ , nítorí náà wọ́ n nífẹ̀ ẹ́ sí lílo èdè ìjìnlẹ̀ tàbí ohun tí ó ní ìtumọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú àṣà wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ . Ọ̀pọ̀ lọpọ̀ onímọ̀ tí ṣiṣẹ́ lórí pàtàkì àrokò láàárín àwọn Yorùbá àmọ́ ọ...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130094
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206113931362304
author Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́
author_facet Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́
author_sort Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́
collection DOAJ
description Àrokò jẹ́ ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ nípa ṣíṣàmúlò àmì tàbí èdè awo. Ìran Yorùbá ò fẹ́ ràn láti máa fi gbogbo ẹnu sọ̀ rọ̀ , nítorí náà wọ́ n nífẹ̀ ẹ́ sí lílo èdè ìjìnlẹ̀ tàbí ohun tí ó ní ìtumọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú àṣà wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ . Ọ̀pọ̀ lọpọ̀ onímọ̀ tí ṣiṣẹ́ lórí pàtàkì àrokò láàárín àwọn Yorùbá àmọ́ ọ̀ wọ́ já wọn ò tí dé ibi àrokò láààrín àwọn babaláwo. Pépà yìí ṣe àgbẹ́ yẹ̀ wò àrokò gẹ́ gẹ́ bíi ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín àwọn babaláwo láwùjọ Yorùbá. Tíọ́ rì ìmọ̀ ìlò-àmi ni a gùnlé láti fi sọ ìtumọ̀ àwọn ohun èlò ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín àwọn bábaláwo. Àwọn détà tí a lò ni a gbà lọ́ dọ̀ àwọn àṣàyàn babaláwo, èyí tí a sì ṣàtúpalẹ̀ wọn pẹ̀ lú tíọ́ rì àmúlò. Iṣẹ́ ìwádìí yìí sàlàyé díẹ̀ lára àwọn ohun ìpàrokò, yálà èyí tí o jẹ́ gbólóhùn tàbí èyí tí o jẹ́ ohun èlò àrídìmú tí àwọn babaláwo ń lò fún ìbánisọ̀ rọ̀ awo láàárín ara wọn pẹ̀ lú ọ̀ nà tí wọn ń gbà lò wọ́ n. Pépà yìí tan ìmọ́ lẹ̀ sí orísìírísìí ohun èlò ìpàrokò àti ọ̀ nà tí àwọn babaláwo ń gbà ṣàmúlò wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín ara wọn. Àpilẹ̀ kọ yìí fi hàn kedere pé ṣíṣe àmúlò àrokò láwùjọ le ṣe ìrànlọ́ wọ́ láti jẹ́ kí á ní àsírí àwọn ohun tí a kò fẹ́ jẹ́ kó hànde. Ó tún jẹ́ kí a mọ̀ pé, kò sí ẹgbẹ́ tàbí àwùjọ kan lábẹ́ àkóso bó ti wù kó rí tí kò ní ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ alárokò láàárín ara wọn.
format Article
id doaj-art-cfaaadbdb7f74a61bbe63ae3b596d7d4
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-cfaaadbdb7f74a61bbe63ae3b596d7d42025-02-07T13:45:04ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́0University of Ibadan Àrokò jẹ́ ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ nípa ṣíṣàmúlò àmì tàbí èdè awo. Ìran Yorùbá ò fẹ́ ràn láti máa fi gbogbo ẹnu sọ̀ rọ̀ , nítorí náà wọ́ n nífẹ̀ ẹ́ sí lílo èdè ìjìnlẹ̀ tàbí ohun tí ó ní ìtumọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú àṣà wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ . Ọ̀pọ̀ lọpọ̀ onímọ̀ tí ṣiṣẹ́ lórí pàtàkì àrokò láàárín àwọn Yorùbá àmọ́ ọ̀ wọ́ já wọn ò tí dé ibi àrokò láààrín àwọn babaláwo. Pépà yìí ṣe àgbẹ́ yẹ̀ wò àrokò gẹ́ gẹ́ bíi ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín àwọn babaláwo láwùjọ Yorùbá. Tíọ́ rì ìmọ̀ ìlò-àmi ni a gùnlé láti fi sọ ìtumọ̀ àwọn ohun èlò ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín àwọn bábaláwo. Àwọn détà tí a lò ni a gbà lọ́ dọ̀ àwọn àṣàyàn babaláwo, èyí tí a sì ṣàtúpalẹ̀ wọn pẹ̀ lú tíọ́ rì àmúlò. Iṣẹ́ ìwádìí yìí sàlàyé díẹ̀ lára àwọn ohun ìpàrokò, yálà èyí tí o jẹ́ gbólóhùn tàbí èyí tí o jẹ́ ohun èlò àrídìmú tí àwọn babaláwo ń lò fún ìbánisọ̀ rọ̀ awo láàárín ara wọn pẹ̀ lú ọ̀ nà tí wọn ń gbà lò wọ́ n. Pépà yìí tan ìmọ́ lẹ̀ sí orísìírísìí ohun èlò ìpàrokò àti ọ̀ nà tí àwọn babaláwo ń gbà ṣàmúlò wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín ara wọn. Àpilẹ̀ kọ yìí fi hàn kedere pé ṣíṣe àmúlò àrokò láwùjọ le ṣe ìrànlọ́ wọ́ láti jẹ́ kí á ní àsírí àwọn ohun tí a kò fẹ́ jẹ́ kó hànde. Ó tún jẹ́ kí a mọ̀ pé, kò sí ẹgbẹ́ tàbí àwùjọ kan lábẹ́ àkóso bó ti wù kó rí tí kò ní ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ alárokò láàárín ara wọn. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130094
spellingShingle Olúwaṣakin A. Kẹhìndé ́
Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
Yoruba Studies Review
title Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
title_full Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
title_fullStr Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
title_full_unstemmed Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
title_short Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo
title_sort aroko gege bi o na ibanisoro laaarin awon babalawo
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130094
work_keys_str_mv AT oluwasakinakehinde arokogegebionaibanisorolaaarinawonbabalawo