Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ede, asa ati litireso je mayami eta-oko to n safihan idanimo awon eniyan kan. Ni orile-ede Naijiria, ede, asa, ati litireso n ko ipa pataki ninu itan won lati igba ti won ti da ekun ariwa ati guusu papo ni odun 1914. ninu aoileko yli, a lo tiori imo ajemotan-tuntun ati tiori imo asa lati sayewo ipa...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Arinpe Adejumo
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130151
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206109313433600
author Arinpe Adejumo
author_facet Arinpe Adejumo
author_sort Arinpe Adejumo
collection DOAJ
description Ede, asa ati litireso je mayami eta-oko to n safihan idanimo awon eniyan kan. Ni orile-ede Naijiria, ede, asa, ati litireso n ko ipa pataki ninu itan won lati igba ti won ti da ekun ariwa ati guusu papo ni odun 1914. ninu aoileko yli, a lo tiori imo ajemotan-tuntun ati tiori imo asa lati sayewo ipa ti ede, asa ati litireso n ko ninu itan, iselu, ibagbepo-eda, eto-oro-aje, esin, ati eto-eko ni orile-ede Naijiria. Arifayo ti a ri ni pe: asa duro bi aaringbungbun fun iselu. Ipo ti awon oba ko ninu iselu olona-ero Lord Lugard si fi pataki asa mule. Bi o tile je pe awon asejoba-amunisin bu enu ate lu ede Yoruba, igbende re ti mu itesiwaju ba imo ero. Litireso Yoruba naa je ohun-elo-ija fun ifi-oju-amuwaye-eni lole ni Naijiria. Imugbooro ti ise ona ise owo, ise ona-alawomo litireso, tilu-tifon, ati fiimu n mu ba eto oro aje naa je jade. Ni ikadii, apileko yil fi idi re mule pe kiko ati mimo ede, asa, ati litireso Yoruba je ohun ti o ye ki a mu ni okunkundun fun igbelaruge asa, ki a si samulo re fun idagbasoke abanikale. 
format Article
id doaj-art-bf57cae876dc443b851b430264699520
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-bf57cae876dc443b851b4302646995202025-02-07T13:44:40ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0112Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè NàìjíríàArinpe Adejumo0University of Ibadan Ede, asa ati litireso je mayami eta-oko to n safihan idanimo awon eniyan kan. Ni orile-ede Naijiria, ede, asa, ati litireso n ko ipa pataki ninu itan won lati igba ti won ti da ekun ariwa ati guusu papo ni odun 1914. ninu aoileko yli, a lo tiori imo ajemotan-tuntun ati tiori imo asa lati sayewo ipa ti ede, asa ati litireso n ko ninu itan, iselu, ibagbepo-eda, eto-oro-aje, esin, ati eto-eko ni orile-ede Naijiria. Arifayo ti a ri ni pe: asa duro bi aaringbungbun fun iselu. Ipo ti awon oba ko ninu iselu olona-ero Lord Lugard si fi pataki asa mule. Bi o tile je pe awon asejoba-amunisin bu enu ate lu ede Yoruba, igbende re ti mu itesiwaju ba imo ero. Litireso Yoruba naa je ohun-elo-ija fun ifi-oju-amuwaye-eni lole ni Naijiria. Imugbooro ti ise ona ise owo, ise ona-alawomo litireso, tilu-tifon, ati fiimu n mu ba eto oro aje naa je jade. Ni ikadii, apileko yil fi idi re mule pe kiko ati mimo ede, asa, ati litireso Yoruba je ohun ti o ye ki a mu ni okunkundun fun igbelaruge asa, ki a si samulo re fun idagbasoke abanikale.  https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130151
spellingShingle Arinpe Adejumo
Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Yoruba Studies Review
title Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
title_full Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
title_fullStr Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
title_full_unstemmed Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
title_short Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
title_sort agbeyewo ipa ede asa ati litireso yoruba ninu ogbagade itan orile ede naijiria
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130151
work_keys_str_mv AT arinpeadejumo agbeyewoipaedeasaatilitiresoyorubaninuogbagadeitanorileedenaijiria