Àìgbọ́ àti àìlèsọ èdè Yorùbá àti àbáyọ fún àwọn ọmọ Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Ohun ti o je mi logun ninu apileko yii ni bi ogooro awon omo bibi ile Yoruba ni ile Amerika ko se le so tabi gbo ede Yoruba. Akiyesi mi ni pe, oro naa dabi oro amukun-un ti eru re ti wo lati ile ni. Mo salaye wi pe ainifee ede Yoruba lokan wa lara isoro ti o n koju opolopo awon omo bibi Yoruba ti w...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Fehintola Mosadomi
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130147
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
Description
Summary:Ohun ti o je mi logun ninu apileko yii ni bi ogooro awon omo bibi ile Yoruba ni ile Amerika ko se le so tabi gbo ede Yoruba. Akiyesi mi ni pe, oro naa dabi oro amukun-un ti eru re ti wo lati ile ni. Mo salaye wi pe ainifee ede Yoruba lokan wa lara isoro ti o n koju opolopo awon omo bibi Yoruba ti won n gbe ni Amerika. Apileko naa gba gbogbo awon omo bibi Naijiria ni imoran pe o ye ki won nifee ede Yoruba, ki won si gbaruku ti kiko ede naa, papaa nipase iranlowo fun awon akomolede Yoruba. 
ISSN:2473-4713
2578-692X