Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe

Òwe jé ọ̀ nà tí à ń gbà láti ṣe àfihàn ìgbéayé è ̣ dá, ìgbàgbó ̣ , àṣà àti ìṣe àwọn ̣ ènìyàn nínú àwùjọ. Saájú kí ètò mò-ọ́ n-kọ, mò ̣ -ọ́ n-kà tó wọ àárin àwọn ènìyàn ̣ dúdú ni ìran Yorùbá ti ní àfojúsùn onírúurú ọgbón ìkó ̣ nilédè abínibí èyí tí wọn ̣ ń ṣàmúlò láti kó tèwe-tàgbà nílà...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Ayọ̀ọlá Ọládùnńkẹ́ Àránsí
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130093
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206020077518848
author Ayọ̀ọlá Ọládùnńkẹ́ Àránsí
author_facet Ayọ̀ọlá Ọládùnńkẹ́ Àránsí
author_sort Ayọ̀ọlá Ọládùnńkẹ́ Àránsí
collection DOAJ
description Òwe jé ọ̀ nà tí à ń gbà láti ṣe àfihàn ìgbéayé è ̣ dá, ìgbàgbó ̣ , àṣà àti ìṣe àwọn ̣ ènìyàn nínú àwùjọ. Saájú kí ètò mò-ọ́ n-kọ, mò ̣ -ọ́ n-kà tó wọ àárin àwọn ènìyàn ̣ dúdú ni ìran Yorùbá ti ní àfojúsùn onírúurú ọgbón ìkó ̣ nilédè abínibí èyí tí wọn ̣ ń ṣàmúlò láti kó tèwe-tàgbà nílànà bí wọn ṣe lè gbé ilé ayé ìrò ̣ rùn pè ̣ lú ìfò ̣ kàn ̣ - balè. Ní àwùjọ Yorùbá gé ̣ gẹ́ bí àwùjọ mìíràn láàrin àwọn è ̣ yà ènìyàn dúdú ní ̣ ilè Ááfíríkà, òwe jé ̣ ilé ìsura ọgbó ̣ n, ìmò ̣ àti òye èyí tó jé ̣ ọgbó ̣ n ìṣàmúlò fún ̣ tawo tògbè ̣ rì láti máa fi kó ̣ àwọn ènìyàn ní ìmò ̣ ìjìnlè ̣ èdè abínibí wọn. Iṣé ̣ yìí ̣ ṣe àfihàn onírúurú ìlànà tí a lè lò láti fi òwe Yorùbá ṣe ìdánilékọ̀ ọ́ tó yè kooro ̣ ní ìbámu pèlú ìgbà àti àsìkò lílo ò ̣ kọ̀ ọ̀ kan wọn àti oríṣìíríṣìí ọgbó ̣ n tí ènìyàn lè ̣ kó nípa ìfòwekó ̣ nilé ̣ kọ̀ ọ́ èyí tó lè mú kí ènìyàn jìnnà sí jíjìn sí ̣ ọ̀ fìn ayé, láti ní àfojúsùn ohun rere àti láti fakọyọ níbikíbi láìmù ìpalara lówọ́ . Ní àfikún, pépà ̣ yìí ṣàgbéyèwò ohun tí òwe jé ̣ , onírúurú ò ̣ nà tí a lè gbà ṣe ìdánilé ̣ kọ̀ ọ́ nílánà ̣ abínibí fún tèwe-tàgbà àti onírúurú ìsòrí òwe fún ìdánilé ̣ kọ̀ ọ́ . Tíó ̣ rì lámèyító ̣ ̣ ìfojú-àṣà-ìbílè-wo ni a lò gé ̣ gẹ́ bí ò ̣ pákùtè ̣ lẹ̀ fún iṣé ̣ yìí.
format Article
id doaj-art-9252832ca5654595b4bf68e640634e8e
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-9252832ca5654595b4bf68e640634e8e2025-02-07T13:45:05ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe Ayọ̀ọlá Ọládùnńkẹ́ Àránsí 0Kwara State University, Malete Òwe jé ọ̀ nà tí à ń gbà láti ṣe àfihàn ìgbéayé è ̣ dá, ìgbàgbó ̣ , àṣà àti ìṣe àwọn ̣ ènìyàn nínú àwùjọ. Saájú kí ètò mò-ọ́ n-kọ, mò ̣ -ọ́ n-kà tó wọ àárin àwọn ènìyàn ̣ dúdú ni ìran Yorùbá ti ní àfojúsùn onírúurú ọgbón ìkó ̣ nilédè abínibí èyí tí wọn ̣ ń ṣàmúlò láti kó tèwe-tàgbà nílànà bí wọn ṣe lè gbé ilé ayé ìrò ̣ rùn pè ̣ lú ìfò ̣ kàn ̣ - balè. Ní àwùjọ Yorùbá gé ̣ gẹ́ bí àwùjọ mìíràn láàrin àwọn è ̣ yà ènìyàn dúdú ní ̣ ilè Ááfíríkà, òwe jé ̣ ilé ìsura ọgbó ̣ n, ìmò ̣ àti òye èyí tó jé ̣ ọgbó ̣ n ìṣàmúlò fún ̣ tawo tògbè ̣ rì láti máa fi kó ̣ àwọn ènìyàn ní ìmò ̣ ìjìnlè ̣ èdè abínibí wọn. Iṣé ̣ yìí ̣ ṣe àfihàn onírúurú ìlànà tí a lè lò láti fi òwe Yorùbá ṣe ìdánilékọ̀ ọ́ tó yè kooro ̣ ní ìbámu pèlú ìgbà àti àsìkò lílo ò ̣ kọ̀ ọ̀ kan wọn àti oríṣìíríṣìí ọgbó ̣ n tí ènìyàn lè ̣ kó nípa ìfòwekó ̣ nilé ̣ kọ̀ ọ́ èyí tó lè mú kí ènìyàn jìnnà sí jíjìn sí ̣ ọ̀ fìn ayé, láti ní àfojúsùn ohun rere àti láti fakọyọ níbikíbi láìmù ìpalara lówọ́ . Ní àfikún, pépà ̣ yìí ṣàgbéyèwò ohun tí òwe jé ̣ , onírúurú ò ̣ nà tí a lè gbà ṣe ìdánilé ̣ kọ̀ ọ́ nílánà ̣ abínibí fún tèwe-tàgbà àti onírúurú ìsòrí òwe fún ìdánilé ̣ kọ̀ ọ́ . Tíó ̣ rì lámèyító ̣ ̣ ìfojú-àṣà-ìbílè-wo ni a lò gé ̣ gẹ́ bí ò ̣ pákùtè ̣ lẹ̀ fún iṣé ̣ yìí. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130093
spellingShingle Ayọ̀ọlá Ọládùnńkẹ́ Àránsí
Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe
Yoruba Studies Review
title Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe
title_full Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe
title_fullStr Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe
title_full_unstemmed Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe
title_short Ọgbọ́n Ìkọ́ni Nímọ̀ Abínibí Pẹ̀lú Òwe
title_sort ogbon ikoni nimo abinibi pelu owe
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130093
work_keys_str_mv AT ayoolaoladunnkearansi ogbonikoninimoabinibipeluowe