Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.

Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn ọ̀jìnmí òǹkọwé lítíré ̀ ṣọ àpil ̀ ẹ̀kọ Yorùbá ní olóògbé Olóyè Ọládẹ̀jọ Òkédìjí jẹ. Ẃ ọn kó àkóyaw ́ ọ́ nínú kíkọ lítíréṣọ̀ Yorùbá. Yàtọ́ sí pé wọn j ́ ẹ́ ògúná gbòǹgbò nídìí kíkọ lítíréṣọ̀ ajẹmọ-ìwà- ́ ọ̀daràn, wọn j ́ ẹ́ òǹkọwé tí ó peregedé nínú kík ̀ ọ́ ìtàn àròsọ, eré-o...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Olusegun Soetan
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130079
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206006221635584
author Olusegun Soetan
author_facet Olusegun Soetan
author_sort Olusegun Soetan
collection DOAJ
description Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn ọ̀jìnmí òǹkọwé lítíré ̀ ṣọ àpil ̀ ẹ̀kọ Yorùbá ní olóògbé Olóyè Ọládẹ̀jọ Òkédìjí jẹ. Ẃ ọn kó àkóyaw ́ ọ́ nínú kíkọ lítíréṣọ̀ Yorùbá. Yàtọ́ sí pé wọn j ́ ẹ́ ògúná gbòǹgbò nídìí kíkọ lítíréṣọ̀ ajẹmọ-ìwà- ́ ọ̀daràn, wọn j ́ ẹ́ òǹkọwé tí ó peregedé nínú kík ̀ ọ́ ìtàn àròsọ, eré-oníṣe, àti ewì. Òdú tí kìí ṣe àimọ̀ fún olóko ní olóyè Òkédìjí láwùjọ àwọn onímọ̀ àti òǹkọwé Yorùbá. ̀ Dí òní, ìwé wọn, Atótó Arére ní ìwé litíréṣọ̀ Yorùbá tí ó gùn jù lọ. Gẹǵ ẹ́ bi òǹkọwé. Olóyè Òkédìjí gbájúm ̀ ọ́ kíkọ àwọn ìtàn tó jẹ mọ ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ ìgbà náà, pàápàá jùlọ àwọn ìwà ọ̀daràn tí ó gbilẹ ní ìlú Ìbàdàn nígbà náà. Bí w ̀ ọn tí ̀ kọ àwọn ìwé tó bẹnu àtẹ́ lu ìwà ìbàjẹ́ àwùjọ, bẹẹ́ ̀ náà ni wọn lo àw ́ ọn ìwé wọn mìíràn láti gba àwùjọ níyànjú. Bákan náà ni wọn ́ ṣíṣọ lórí eégún, tí wọn sì ́ f irú ìyà tó ń jẹ àwọn òṣìṣẹ́ hànde. Nígbà tí ogbó dé, wọn b ́ ẹr̀ ẹ̀ síí kọ àwọn èwí tí ó lè fún àwọn òǹkàwé ní ìmísí láti ṣíṣẹ́ takuntakun, àti láti gbani nímọràn. ̀ Bí ó tilẹ j̀ ẹ pé olóyé Òkédìjí kò sí láyé m ́ ọ lónìí, síb ̀ ẹ, mánigbàgbé ní àw ́ ọn ìwé ti wọn k ́ ọ jẹ. ́ Ó kù sáàtà kí wọn papòda ní ìf ́ ọr̀ ọwanil ̀ ẹnuwò yìí wáyé niléé w ́ ọn ní ìlú Ọỳ ọ, ní ̀ ọjọ ḱ ọkàndínlógún, oṣu kẹwàá, ọdún 2018. Nínú ìfọr̀ọwánil ̀ ẹnuwò yìí, ́ Olóyè Òkédìjí mẹnuba ́ ọgbọn ìs ́ ọtàn w ̀ ọn, ìṣòro tó ń dojúkọ lítíréṣọ̀ Yorùbá, àtí ìpèníjà tó dé bá jíjẹ ò́ ǹkọwé alátinúdá ní àwùj ̀ ọ wa, àti ní orílẹ-èdè Nàíjíríà.
format Article
id doaj-art-690e762082614b6991eaef55bd13a844
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-690e762082614b6991eaef55bd13a8442025-02-07T13:45:10ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0151Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní. Olusegun Soetan 0Pennsylvania University Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn ọ̀jìnmí òǹkọwé lítíré ̀ ṣọ àpil ̀ ẹ̀kọ Yorùbá ní olóògbé Olóyè Ọládẹ̀jọ Òkédìjí jẹ. Ẃ ọn kó àkóyaw ́ ọ́ nínú kíkọ lítíréṣọ̀ Yorùbá. Yàtọ́ sí pé wọn j ́ ẹ́ ògúná gbòǹgbò nídìí kíkọ lítíréṣọ̀ ajẹmọ-ìwà- ́ ọ̀daràn, wọn j ́ ẹ́ òǹkọwé tí ó peregedé nínú kík ̀ ọ́ ìtàn àròsọ, eré-oníṣe, àti ewì. Òdú tí kìí ṣe àimọ̀ fún olóko ní olóyè Òkédìjí láwùjọ àwọn onímọ̀ àti òǹkọwé Yorùbá. ̀ Dí òní, ìwé wọn, Atótó Arére ní ìwé litíréṣọ̀ Yorùbá tí ó gùn jù lọ. Gẹǵ ẹ́ bi òǹkọwé. Olóyè Òkédìjí gbájúm ̀ ọ́ kíkọ àwọn ìtàn tó jẹ mọ ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ ìgbà náà, pàápàá jùlọ àwọn ìwà ọ̀daràn tí ó gbilẹ ní ìlú Ìbàdàn nígbà náà. Bí w ̀ ọn tí ̀ kọ àwọn ìwé tó bẹnu àtẹ́ lu ìwà ìbàjẹ́ àwùjọ, bẹẹ́ ̀ náà ni wọn lo àw ́ ọn ìwé wọn mìíràn láti gba àwùjọ níyànjú. Bákan náà ni wọn ́ ṣíṣọ lórí eégún, tí wọn sì ́ f irú ìyà tó ń jẹ àwọn òṣìṣẹ́ hànde. Nígbà tí ogbó dé, wọn b ́ ẹr̀ ẹ̀ síí kọ àwọn èwí tí ó lè fún àwọn òǹkàwé ní ìmísí láti ṣíṣẹ́ takuntakun, àti láti gbani nímọràn. ̀ Bí ó tilẹ j̀ ẹ pé olóyé Òkédìjí kò sí láyé m ́ ọ lónìí, síb ̀ ẹ, mánigbàgbé ní àw ́ ọn ìwé ti wọn k ́ ọ jẹ. ́ Ó kù sáàtà kí wọn papòda ní ìf ́ ọr̀ ọwanil ̀ ẹnuwò yìí wáyé niléé w ́ ọn ní ìlú Ọỳ ọ, ní ̀ ọjọ ḱ ọkàndínlógún, oṣu kẹwàá, ọdún 2018. Nínú ìfọr̀ọwánil ̀ ẹnuwò yìí, ́ Olóyè Òkédìjí mẹnuba ́ ọgbọn ìs ́ ọtàn w ̀ ọn, ìṣòro tó ń dojúkọ lítíréṣọ̀ Yorùbá, àtí ìpèníjà tó dé bá jíjẹ ò́ ǹkọwé alátinúdá ní àwùj ̀ ọ wa, àti ní orílẹ-èdè Nàíjíríà. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130079
spellingShingle Olusegun Soetan
Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
Yoruba Studies Review
title Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
title_full Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
title_fullStr Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
title_full_unstemmed Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
title_short Conversation with Ọladẹjọ Okediji: Lítíréṣọ̀ Àpilẹ̀kọ Yorùbá Látijọ́ àti Lódeòní.
title_sort conversation with oladejo okediji litireso apileko yoruba latijo ati lodeoni
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130079
work_keys_str_mv AT olusegunsoetan conversationwitholadejookedijilitiresoapilekoyorubalatijoatilodeoni