Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà

Ọ̀pọ̀ ọ̀ nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún síṣe àwárí tàbí ìṣẹ̀ dá ọ̀ rọ̀ -ìperí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìsàlàyé, ìhun-ọ̀rọ̀-pọ̀ , ìfisàpẹrẹ, ìlòwe, ọ̀ rọ̀ -àyálò, ìfẹ[1]ìtumọ̀ -lójú àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ. Ìfẹ-ìtumọ̀ lójú ni ó jẹ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá ọ̀ rọ̀ ìperí fún àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Clement Odoje
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130095
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206077793239040
author Clement Odoje
author_facet Clement Odoje
author_sort Clement Odoje
collection DOAJ
description Ọ̀pọ̀ ọ̀ nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún síṣe àwárí tàbí ìṣẹ̀ dá ọ̀ rọ̀ -ìperí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìsàlàyé, ìhun-ọ̀rọ̀-pọ̀ , ìfisàpẹrẹ, ìlòwe, ọ̀ rọ̀ -àyálò, ìfẹ[1]ìtumọ̀ -lójú àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ. Ìfẹ-ìtumọ̀ lójú ni ó jẹ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá ọ̀ rọ̀ ìperí fún àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara ̣ (KASA) àti Èbólà. A ṣe àgbéyẹ̀ wò 1572 ọ̀ rọ̀ tí Yusuff, Adétúnjí àti Odoje (2017) jẹ́ olóòtú fún, a sì fa àwọn tí wọ́ n fẹ ìtumọ̀ wọn lójú yọ fún ìṣẹ́ ìwádìí ti wa. A ṣàwárí pé oríṣìí mẹ́ tà ọ̀ tọ̀ ọ̀ tọ̀ ni irú àwọn ọ̀ rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wà wọ àwọn ọ̀ rọ̀ náà lọ́ rùn. Ó tilẹ̀ mú ìtumọ̀ gbéetán bá àwọn ọ̀ rọ̀ tuntun tí a lò wọ́ n fún.
format Article
id doaj-art-562cf8c07ad045b89b60a384d94f545b
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-562cf8c07ad045b89b60a384d94f545b2025-02-07T13:45:04ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà Clement Odoje0University of Ibadan Ọ̀pọ̀ ọ̀ nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún síṣe àwárí tàbí ìṣẹ̀ dá ọ̀ rọ̀ -ìperí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìsàlàyé, ìhun-ọ̀rọ̀-pọ̀ , ìfisàpẹrẹ, ìlòwe, ọ̀ rọ̀ -àyálò, ìfẹ[1]ìtumọ̀ -lójú àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ. Ìfẹ-ìtumọ̀ lójú ni ó jẹ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá ọ̀ rọ̀ ìperí fún àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara ̣ (KASA) àti Èbólà. A ṣe àgbéyẹ̀ wò 1572 ọ̀ rọ̀ tí Yusuff, Adétúnjí àti Odoje (2017) jẹ́ olóòtú fún, a sì fa àwọn tí wọ́ n fẹ ìtumọ̀ wọn lójú yọ fún ìṣẹ́ ìwádìí ti wa. A ṣàwárí pé oríṣìí mẹ́ tà ọ̀ tọ̀ ọ̀ tọ̀ ni irú àwọn ọ̀ rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wà wọ àwọn ọ̀ rọ̀ náà lọ́ rùn. Ó tilẹ̀ mú ìtumọ̀ gbéetán bá àwọn ọ̀ rọ̀ tuntun tí a lò wọ́ n fún. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130095
spellingShingle Clement Odoje
Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
Yoruba Studies Review
title Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
title_full Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
title_fullStr Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
title_full_unstemmed Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
title_short Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
title_sort ife itumo loju wiwa oro iperi fun arun kokoro apa soja ara kasa ati ebola
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130095
work_keys_str_mv AT clementodoje ifeitumolojuwiwaoroiperifunarunkokoroapasojaarakasaatiebola