Èdè Yorùbá, ọ̀rọ̀ àyálò, àti ọ̀rọ̀ àdàpọ̀ àti akẹ́kọ̀ọ́ kíkọ́ ní ìlú Amẹ́ríkà
Ero mi ninu apileko yii da lori awon oro ayalo ninu ede Yoruba nipase ajosepo ti o ti wa laarin ede naa ati ede Oyinbo ni orile-ede Naijiria. Mo salaye wi pe eyi ki i se tuntun rara nitori pe ba kan naa ni omo sori bi ede meji ba ni ajosepo. Apileko naa menu ba awon isoro ti awon oro ayalo wonyi le...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130146 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Be the first to leave a comment!