Èdè Yorùbá, ọ̀rọ̀ àyálò, àti ọ̀rọ̀ àdàpọ̀ àti akẹ́kọ̀ọ́ kíkọ́ ní ìlú Amẹ́ríkà

Ero mi ninu apileko yii da lori awon oro ayalo ninu ede Yoruba nipase ajosepo ti o ti wa laarin ede naa ati ede Oyinbo ni orile-ede Naijiria. Mo salaye wi pe eyi ki i se tuntun rara nitori pe ba kan naa ni omo sori bi ede meji ba ni ajosepo. Apileko naa menu ba awon isoro ti awon oro ayalo wonyi le...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Victor Temitope Alabi
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130146
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
Description
Summary:Ero mi ninu apileko yii da lori awon oro ayalo ninu ede Yoruba nipase ajosepo ti o ti wa laarin ede naa ati ede Oyinbo ni orile-ede Naijiria. Mo salaye wi pe eyi ki i se tuntun rara nitori pe ba kan naa ni omo sori bi ede meji ba ni ajosepo. Apileko naa menu ba awon isoro ti awon oro ayalo wonyi le da sile fun awon akekoo ti won n ko ede Yoruba gege bi ede akokunteni. Nipari, a gba awon oluko nimoran lori awon ogbon ikoni ti yoo wulo pupo fun ise won.
ISSN:2473-4713
2578-692X