Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá

 Òkan pàtàkì lára lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ni oríkì jẹ́, àwọn onímọ̀ lọ́kan- ̣ ò-jò kan ló sì ti wale ̣ ̀ jin lórí oríkì ṣùgbọ́n kò tí sí iṣẹ́ ìwádìí kan gbòógì tí ó ̣ jẹyọ lórí ìfarajọ-èébú nínú oríkì Yorùbá. Láti di àlàfo yìí, iṣé...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Abídèmi. O. Bọlárìnwá
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130098
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206072673042432
author Abídèmi. O. Bọlárìnwá
author_facet Abídèmi. O. Bọlárìnwá
author_sort Abídèmi. O. Bọlárìnwá
collection DOAJ
description  Òkan pàtàkì lára lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ni oríkì jẹ́, àwọn onímọ̀ lọ́kan- ̣ ò-jò kan ló sì ti wale ̣ ̀ jin lórí oríkì ṣùgbọ́n kò tí sí iṣẹ́ ìwádìí kan gbòógì tí ó ̣ jẹyọ lórí ìfarajọ-èébú nínú oríkì Yorùbá. Láti di àlàfo yìí, iṣẹ́ ìwádìí yìí fi tíọ́rì ìfìwádìí-sọ̀tumọ̀ ṣe àtẹ̀gùn láti ṣe àyẹ̀wò àwọn oríṣìí oríkì Yorùbá mẹ́ta tí ìfarajọ-èébú jẹyọ nínú wọn, èyí tí a ṣe àfàyọ wọ́n láti inú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tí a ṣe àti iṣẹ́ àpilẹ̀kọ àwọn onímọ̀. Àwọn oríkì náà ni oríkì orílẹ̀, oríkì àmútọ̀runwá àti oríkì ìlú. Ìwádìí yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé gbogbo àwọn ìpèdè tí ó farajọ èébú àti ìtìjú fún àwọn ènìyàn ní àwùjọ Yorùbá ni wó n kì í ṣe èébú ṣùgbọ́n tí wọ́n jẹ́ ̣ ohun àmúyangàn, ohun ọlá àti ẹ̀yẹ ní ìgbà tí a bá ti sọ ó di oríkì tí a sì fi ń ki ̣ àwọn olóríkì. Ohun ti èyí ń tọ́ka sí ni pé, àwọn àṣà àti èrò Yorùbá nípa èébú àti àbùkù máa ń yípadà ní ìgbà tí a bá ṣàmúlò wọn gẹ́gẹ́ bí oríkì ní ilẹ̀ Yorùbá, torí kì í ṣe èébú mọ́ ṣùgbọ́n ìtọ́ka sí ìtàn àti ìṣe akọni olóríkì ni.
format Article
id doaj-art-441e6e746bf54030bfc5c453bfec28db
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-441e6e746bf54030bfc5c453bfec28db2025-02-07T13:45:02ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá Abídèmi. O. Bọlárìnwá 0University of Ibadan  Òkan pàtàkì lára lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ni oríkì jẹ́, àwọn onímọ̀ lọ́kan- ̣ ò-jò kan ló sì ti wale ̣ ̀ jin lórí oríkì ṣùgbọ́n kò tí sí iṣẹ́ ìwádìí kan gbòógì tí ó ̣ jẹyọ lórí ìfarajọ-èébú nínú oríkì Yorùbá. Láti di àlàfo yìí, iṣẹ́ ìwádìí yìí fi tíọ́rì ìfìwádìí-sọ̀tumọ̀ ṣe àtẹ̀gùn láti ṣe àyẹ̀wò àwọn oríṣìí oríkì Yorùbá mẹ́ta tí ìfarajọ-èébú jẹyọ nínú wọn, èyí tí a ṣe àfàyọ wọ́n láti inú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tí a ṣe àti iṣẹ́ àpilẹ̀kọ àwọn onímọ̀. Àwọn oríkì náà ni oríkì orílẹ̀, oríkì àmútọ̀runwá àti oríkì ìlú. Ìwádìí yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé gbogbo àwọn ìpèdè tí ó farajọ èébú àti ìtìjú fún àwọn ènìyàn ní àwùjọ Yorùbá ni wó n kì í ṣe èébú ṣùgbọ́n tí wọ́n jẹ́ ̣ ohun àmúyangàn, ohun ọlá àti ẹ̀yẹ ní ìgbà tí a bá ti sọ ó di oríkì tí a sì fi ń ki ̣ àwọn olóríkì. Ohun ti èyí ń tọ́ka sí ni pé, àwọn àṣà àti èrò Yorùbá nípa èébú àti àbùkù máa ń yípadà ní ìgbà tí a bá ṣàmúlò wọn gẹ́gẹ́ bí oríkì ní ilẹ̀ Yorùbá, torí kì í ṣe èébú mọ́ ṣùgbọ́n ìtọ́ka sí ìtàn àti ìṣe akọni olóríkì ni. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130098
spellingShingle Abídèmi. O. Bọlárìnwá
Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
Yoruba Studies Review
title Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
title_full Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
title_fullStr Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
title_full_unstemmed Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
title_short Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
title_sort ifarajo eebu ninu awon asayan oriki yoruba
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130098
work_keys_str_mv AT abidemiobolarinwa ifarajoeebuninuawonasayanorikiyoruba