Wútùwútù Yáákí
Wútùwútù yáákí; Wútùwútù yám̀bèlé; Ká súré pátápirá, Ká fè wù àlàárì fọnkun àmódi; ̣ Ẹsẹ Ifá yìí jé ọ ̀ kan nínú àwọn ifá ńláńlá tí a fà yọ kúrò nínú Òtúá Méjì. Méjì ̣ ni àwọn onímò -èdè Yorùbá tó ti yẹ ẹsẹ Ifá wò...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130107 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Summary: | Wútùwútù yáákí;
Wútùwútù yám̀bèlé;
Ká súré pátápirá,
Ká fè wù àlàárì fọnkun àmódi; ̣
Ẹsẹ Ifá yìí jé ọ ̀ kan nínú àwọn ifá ńláńlá tí a fà yọ kúrò nínú Òtúá Méjì. Méjì ̣ ni àwọn onímò -èdè Yorùbá tó ti yẹ ẹsẹ Ifá wò fínífíní pe ̣ ̀ lú ìjìnle ̣ ̀ ìmọ̀ òde òní ̣ nípa èdè tí a ń pè ní lìǹgúísítíkì. Ẹni àkó kọ ́ , Ọ ̀gbe ̣ ́ ni ’Wáǹdé Abímbo ̣ ́ lá la ẹsẹ ̣ Ifá sí ò nà me ̣ ́ jọ.4 Ọlátúndé Ọlátúnjí ni ẹnì kejì; òun pín ẹsẹ Ifá sí ìsò rí méje.5 Gé gẹ ́ bí a ó ṣe rí i ní ìsàle ̣ ̀ (ẹ wo àlàyé 2), àwọn àye ̣ ̀ wò méjèèjì tí a dárúkọ ̣ wò nyí pọwo ̣ ̣ ́ léra. Nínú àdìtú wa yìí, ètò ẹsẹ Ifá onídàáméje ni a ó mùú lò nítorí pé ó dà bí ẹní bá ẹsẹ Ifá yìí mu jù lọ. Nínú ìdá èkìíní (Ìlà 1 dé 8), a lè pín àwọn gbólóhùn ibè sí oríṣìí meta.
|
---|---|
ISSN: | 2473-4713 2578-692X |