Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni

O pon dandan lati wa ona ti awon ajoji ti won nifee lati ko ati lati mo ede Yoruba yoo gba ti yoo fi ro won lorun lai si pe kiko ede Yoruba n ko won lominu. Idi pataki ni pe ogooro ninu awon ti o fe ko ede yii ni o je wi pe ki i se fun siso nikan tabi kiko lerefee, bikose pe won fe ni imo ti o kun...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Harrison Adeniyi
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130143
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206062537506816
author Harrison Adeniyi
author_facet Harrison Adeniyi
author_sort Harrison Adeniyi
collection DOAJ
description O pon dandan lati wa ona ti awon ajoji ti won nifee lati ko ati lati mo ede Yoruba yoo gba ti yoo fi ro won lorun lai si pe kiko ede Yoruba n ko won lominu. Idi pataki ni pe ogooro ninu awon ti o fe ko ede yii ni o je wi pe ki i se fun siso nikan tabi kiko lerefee, bikose pe won fe ni imo ti o kun ti awon naa yoo fi le se bi omo bibi Yoruba. Eko gbigbona ni oro kiko girama ede je, o n fe suuru gidigidi. Nitori idi eyi, awa Oluko ede Yoruba ni lati wa ona ti yoo je ki kiko ati mimo ede Yoruba ati paapaa girama ede, dabi pe a n fi eran jeko. Ohun ti yoo je wa logun ju ninu ise yii ni pe a o wo bi a se le ko awon akekoo yii, ti won tun je ajoji, ni girama ede Yoruba lai si pe a le won sa lati ko ati lati mo ede yii. A o wo gbogbo awon ohun ti o ye ki awon akekoo mo ninu girama ede Yoruba, awon ipele ti o ye ki won ti mo on ati bi o ti ye ki a ko won ni ipele kookan. A o beere, a o si tun dahun idi ti awon ajoji fi nifee lati ko ati lati mo ede Yoruba. Gbogbo ohun ti o ye ki o wa ninu akoonu ti akekoo gbodo mo ni a o ye wo finnifinni. Leyin eyi, a o tun wo gbogbo ogbon ikoni ti a le lo ti yoo fi je ki kiko girama ede rorun fun wa lati ko, ki o si tun rorun fun awon akekoo lati mo. Leyin eyi, a o soro lekun-un rere lori bi o se ye ki a ko awon akekoo yii ni akodunnu ti yoo fi je ki ede Yoruba wu won lopolopo.
format Article
id doaj-art-2dc754bf8e1b4815a34840e979cdd2d2
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-2dc754bf8e1b4815a34840e979cdd2d22025-02-07T13:44:43ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0112Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́niHarrison Adeniyi0Lagos State University O pon dandan lati wa ona ti awon ajoji ti won nifee lati ko ati lati mo ede Yoruba yoo gba ti yoo fi ro won lorun lai si pe kiko ede Yoruba n ko won lominu. Idi pataki ni pe ogooro ninu awon ti o fe ko ede yii ni o je wi pe ki i se fun siso nikan tabi kiko lerefee, bikose pe won fe ni imo ti o kun ti awon naa yoo fi le se bi omo bibi Yoruba. Eko gbigbona ni oro kiko girama ede je, o n fe suuru gidigidi. Nitori idi eyi, awa Oluko ede Yoruba ni lati wa ona ti yoo je ki kiko ati mimo ede Yoruba ati paapaa girama ede, dabi pe a n fi eran jeko. Ohun ti yoo je wa logun ju ninu ise yii ni pe a o wo bi a se le ko awon akekoo yii, ti won tun je ajoji, ni girama ede Yoruba lai si pe a le won sa lati ko ati lati mo ede yii. A o wo gbogbo awon ohun ti o ye ki awon akekoo mo ninu girama ede Yoruba, awon ipele ti o ye ki won ti mo on ati bi o ti ye ki a ko won ni ipele kookan. A o beere, a o si tun dahun idi ti awon ajoji fi nifee lati ko ati lati mo ede Yoruba. Gbogbo ohun ti o ye ki o wa ninu akoonu ti akekoo gbodo mo ni a o ye wo finnifinni. Leyin eyi, a o tun wo gbogbo ogbon ikoni ti a le lo ti yoo fi je ki kiko girama ede rorun fun wa lati ko, ki o si tun rorun fun awon akekoo lati mo. Leyin eyi, a o soro lekun-un rere lori bi o se ye ki a ko awon akekoo yii ni akodunnu ti yoo fi je ki ede Yoruba wu won lopolopo. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130143
spellingShingle Harrison Adeniyi
Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni
Yoruba Studies Review
title Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni
title_full Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni
title_fullStr Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni
title_full_unstemmed Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni
title_short Kíkọ́ Àjòjì Ní Gírámà Èdè Yorùbá: Àkóónú Àti Ọgbọ́n-Ìkọ́ni
title_sort kiko ajoji ni girama ede yoruba akoonu ati ogbon ikoni
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130143
work_keys_str_mv AT harrisonadeniyi kikoajojinigiramaedeyorubaakoonuatiogbonikoni