Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì
Onírúurú ọdún ìbílẹ̀ ló wà láàrin Yorùbá, ọ̀ kan-ò-jọ̀ kan ìbọ ni wọ́ n sì máa ń fi sọrí àwọn ọdún ìbílẹ̀ wọ̀ nyí. Ó fẹ́ rẹ̀ ẹ́ má sí ìlú kan láwùjọ Yorùbá tí kò ní ọdún ìbílẹ̀ kan tí wọ́ n ń ṣe ní pàtó. Ọ̀rọ̀ nípa ìbọ àti ọdún ìbílẹ̀ kì í ṣe àjò...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130102 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
_version_ | 1825206053981126656 |
---|---|
author | Rifqat Ọpẹyẹmí Sanni ́ |
author_facet | Rifqat Ọpẹyẹmí Sanni ́ |
author_sort | Rifqat Ọpẹyẹmí Sanni ́ |
collection | DOAJ |
description |
Onírúurú ọdún ìbílẹ̀ ló wà láàrin Yorùbá, ọ̀ kan-ò-jọ̀ kan ìbọ ni wọ́ n sì máa ń fi sọrí àwọn ọdún ìbílẹ̀ wọ̀ nyí. Ó fẹ́ rẹ̀ ẹ́ má sí ìlú kan láwùjọ Yorùbá tí kò ní ọdún ìbílẹ̀ kan tí wọ́ n ń ṣe ní pàtó. Ọ̀rọ̀ nípa ìbọ àti ọdún ìbílẹ̀ kì í ṣe àjòjì ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní pàtàkì jù lọ láàrin àwọn Àwórì. Onírúurú iṣẹ́ akadá ni ó ti wà nílẹ̀ lórí ewì alohùn inú àwọn ọdún ìbílẹ̀ àti ìbọ ilẹ̀ Yorùba ṣùgbọ́ n kò sí èyíkéyìí nínú àwọn tí a ka tí ó gbájú mọ́ ìbọbìnrin láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ Èkó tàbí ewì inú ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn tí iṣẹ́ yìí dá lé. Èyí mú kí á lè sọ pé, kò tí ì sí ìtúpalẹ̀ ewì ìbọbìnrin láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ Èkó tí a rí. Èròǹgbà wa nínú iṣẹ́ yìí ni láti ṣe ìtúpalẹ̀ ewì àti iṣẹ́ -ọnà inú ìbọ Aláwòrò- Ẹkùn láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ Èkó. A kò fi òdiwọn sí ewì alohun tí a múlò, a ṣe àgbàsílẹ̀ gbogbo èyí tí a bá pàdé nínú bíbọ Aláwòrò-Ẹkùn. A sì tún ṣe ìfọ̀ rọ̀ -wáni-lẹ́ nu-wò fún abọrẹ̀ Aláwòrò-Ẹkùn àti àwọn olùsìn mẹ́ ta. A ṣe ìtúpalẹ̀ àbọ̀ ìwádìí pẹ̀ lú tíọ́ rì ìfìwádìí-sọ̀ tumọ̀ àti tíọ́ rì jẹ́ ńdà. Èyí jẹ́ kí a ní òye pé, takọ-tabo ló ni ipa tí wọ́ n ń kó nínú ọdún àti bíbọ ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn, bẹ́ ẹ̀ ni a rí ihà tí obìnrin kọ sí ọkùnrin, ìhà tí ọkùnrin kọ sí obìnrin, àti ìhà tí àwọn obìnrin kọ sí ara wọn ní ojúbọ. Ohun gbogbo tí a tọ́ ka sí nípa ewì alohùn Aláwòrò-Ẹkùn àti ìlò ohun èlò pọ̀ mọ́ ewì alohùn wọ̀ nyí jẹ́ kí a lè sọ pé ipa pàtàkì ni àwọn ewì alohùn ń kó nínú bíbọ ìbọ àti ọdún láwùjọ Yorùbá, àti ní pàtàkì jùlọ nínú ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ̀ Èkó.
|
format | Article |
id | doaj-art-07599d3b207d4c74947d8b69a55a637d |
institution | Kabale University |
issn | 2473-4713 2578-692X |
language | English |
publishDate | 2021-12-01 |
publisher | LibraryPress@UF |
record_format | Article |
series | Yoruba Studies Review |
spelling | doaj-art-07599d3b207d4c74947d8b69a55a637d2025-02-07T13:45:00ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì Rifqat Ọpẹyẹmí Sanni ́ 0Adeniran Ogunsanya College of Education Onírúurú ọdún ìbílẹ̀ ló wà láàrin Yorùbá, ọ̀ kan-ò-jọ̀ kan ìbọ ni wọ́ n sì máa ń fi sọrí àwọn ọdún ìbílẹ̀ wọ̀ nyí. Ó fẹ́ rẹ̀ ẹ́ má sí ìlú kan láwùjọ Yorùbá tí kò ní ọdún ìbílẹ̀ kan tí wọ́ n ń ṣe ní pàtó. Ọ̀rọ̀ nípa ìbọ àti ọdún ìbílẹ̀ kì í ṣe àjòjì ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní pàtàkì jù lọ láàrin àwọn Àwórì. Onírúurú iṣẹ́ akadá ni ó ti wà nílẹ̀ lórí ewì alohùn inú àwọn ọdún ìbílẹ̀ àti ìbọ ilẹ̀ Yorùba ṣùgbọ́ n kò sí èyíkéyìí nínú àwọn tí a ka tí ó gbájú mọ́ ìbọbìnrin láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ Èkó tàbí ewì inú ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn tí iṣẹ́ yìí dá lé. Èyí mú kí á lè sọ pé, kò tí ì sí ìtúpalẹ̀ ewì ìbọbìnrin láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ Èkó tí a rí. Èròǹgbà wa nínú iṣẹ́ yìí ni láti ṣe ìtúpalẹ̀ ewì àti iṣẹ́ -ọnà inú ìbọ Aláwòrò- Ẹkùn láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ Èkó. A kò fi òdiwọn sí ewì alohun tí a múlò, a ṣe àgbàsílẹ̀ gbogbo èyí tí a bá pàdé nínú bíbọ Aláwòrò-Ẹkùn. A sì tún ṣe ìfọ̀ rọ̀ -wáni-lẹ́ nu-wò fún abọrẹ̀ Aláwòrò-Ẹkùn àti àwọn olùsìn mẹ́ ta. A ṣe ìtúpalẹ̀ àbọ̀ ìwádìí pẹ̀ lú tíọ́ rì ìfìwádìí-sọ̀ tumọ̀ àti tíọ́ rì jẹ́ ńdà. Èyí jẹ́ kí a ní òye pé, takọ-tabo ló ni ipa tí wọ́ n ń kó nínú ọdún àti bíbọ ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn, bẹ́ ẹ̀ ni a rí ihà tí obìnrin kọ sí ọkùnrin, ìhà tí ọkùnrin kọ sí obìnrin, àti ìhà tí àwọn obìnrin kọ sí ara wọn ní ojúbọ. Ohun gbogbo tí a tọ́ ka sí nípa ewì alohùn Aláwòrò-Ẹkùn àti ìlò ohun èlò pọ̀ mọ́ ewì alohùn wọ̀ nyí jẹ́ kí a lè sọ pé ipa pàtàkì ni àwọn ewì alohùn ń kó nínú bíbọ ìbọ àti ọdún láwùjọ Yorùbá, àti ní pàtàkì jùlọ nínú ìbọ Aláwòrò-Ẹkùn láàrin àwọn Àwórì ní ìpínlẹ̀ Èkó. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130102 |
spellingShingle | Rifqat Ọpẹyẹmí Sanni ́ Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì Yoruba Studies Review |
title | Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì |
title_full | Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì |
title_fullStr | Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì |
title_full_unstemmed | Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì |
title_short | Ìtúpalẹ̀ Ewì Aláwòrò-Ẹkùn Láàrin Àwọn Àwórì |
title_sort | itupale ewi alaworo ekun laarin awon awori |
url | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130102 |
work_keys_str_mv | AT rifqatopeyemisanni itupaleewialaworoekunlaarinawonawori |